Oriki of Egba land

0

The eulogy(oriki) of Egba land is as follows;

 • Ẹ̀gbá mo’lisa
 • Omo gbongbo akala
 • Omo erin jogun ola
 • Omo osi’lekun pa’lekun de
 • Aridi ogo loju Ogun
 • Baba t’emi la royin ogun baara fagbe
 • Ko sohun ti won n se ni mecca
 • T’awa kii se Legba Alake
 • Won n mumi semi semi ni Mecca
 • Awa n mumi Odo Ogun legba Alake
 • Won n g’Arafa ni Mecca
 • Awa n gori Olumo l’egba tiwa
 • Won bimi L’ake
 • Mo gbo lenu bi jeje
 • Won bimi ni Gbagura
 • Mo gbo lohun bi oje
 • Egba meji kin jarawon niyan

Leave a Reply